| 
	    
	| 
		
	 | 
    
 Songs    | Albums    | Album Arts 
 
| Song: | Bahia | 
 
| Album: | Djin Djin | Genres: |   |  
| Year: |   | Length: | 214 sec | 
 
Lyrics: 
 Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè Ouidah ni ilé ti bahia Ti émin mon wa, ri yin lénin o
  Bahia, bahia, bahia, bahia, bahia, bahia
  Ilé ti babawa djinan, awa fè lolé Bahia ilou ti awa lenin, okpè gan si ilé
  Ogun ti awon agbalagba, shé kalè foun wa o Logbé wa lo si bahia, gbé gbogbowa kpo
  Bahia, bahia, bahia, bahia, bahia, bahia
  Odjo ikadé wa m'bowa o, ti ale rira wa Ewa ka moura foun odjo yin, ninou oyaya Oluwa foun wa ni ayé, edjè ka du kpè Bahia kpa gbogbowa kpo, iréti wa lonan
  Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè Ouidah ni ilé ti bahia Ti émin mon wa, ri yin lénin o
  Oré ifé ayé ilé, oré ifé ayé ilé...
  Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè Ouidah ni ilé ti bahia Ti émin mon wa, ri yin lénin o
  Oré ifé ayé ilé, oré ifé ayé ilé... 
	
 | 
	
        All lyrics are property and copyright of their owners. 
        2025 Zortam.com  
        
     |